Omo olukotun Taiwo srt

Omo olukotun Taiwo srt

Share

Afenifere Tv

16/06/2026
16/06/2026

HA! EEMO WOLU!!!
Okere tán ọba 30 ni ile Yoruba lo ti sá kúrò ní Afin nítorí àwọn Bandits Ajinigbe.

Èyín ni àwọn ọba tí wọ́n tí jigbe tí wọ́n sì ti ṣe ikú pa nínú wọn.

Ní ana òde yí ní wón jí Ọba Adeniyi Adelana gbé ní ilu ọwọ n'ipinle Ondo tí wọ́n sì yinbọn fún ìyáwo rẹ. 😭

👇👇👇👇👇👇

1. Oba Kehinde Jacob Falodun – Alagamo of Agamo, Akure North LGA, Ondo State

2. Oba Segun Aremu / Oba Olusegun Aremu-Cole – Olukoro of Koro, Ekiti LGA, Kwara State

3. Oba David Babatunde Ogunsakin – Elesun of Esun-Ekiti, Ekiti State

4. Oba Samuel Olatunji Olusola / Oba Olatunde Samuel Olusola – Onimojo of Imojo-Ekiti, Ekiti State

5. Oba Adegoke Adeusi – Olufon of Ifon, Ondo State

6. Baale of Ogbayo – Oke-Ode, Ifelodun LGA, Kwara State wọn ti pa kí Ọlọhun Ọba kò ṣe ikú ni ìsinmi fún wọn.

7. Oba Salman Olátúnjí Aweda – Asamu of Olayinka, Ifelodun LGA, Kwara State wọn ti pa kí Ọlọhun Ọba kò tẹ sì afẹ́fẹ́ ire àmín

8. Oba J.D. Ogunyanda Ilufemiloye / Oba James Dada Ogunyanda – Obalohun of Okoloke, Yagba West LGA, Kogi State

9. Ojibara of Bayagan-Ile, Oba Kamilu Salami – Kwara State

10. Oba Simeon Olaonipekun – Oniwo of Afin, Ifelodun LGA, Kwara State

11. Adeniyi Adelana – Traditional ruler of Ode Oriya Village, Owo LGA, Ondo State wọn ṣẹ̀ṣẹ̀ gbé àwọn ni ana òde yí ní.

Ṣe bí a ó ṣe má bá lọ náà nìyí lórílẹ̀ èdè Yorùbá.
Ọlọhun Ọba lawa nínú aburu orile-ede Naijiria yí óò àmín.

Credit: Yorùbá dùn ún ká

15/06/2026

Eemo Wolu Oo!! E Gba Wa Oo!! Ogun De
Awon Agbesunmomi Afemisofo Ti Won Ji Oga Ologun 🪖 General Gbe Ni Aro Oni Awon Agbesunmomi Afemisofo Gbe Oku Oga Ologun 🪖 Ti Won Pa Wa Si Arin Ilu,
Won Gbe Oku Naa Fun Awon Osise Ijoba ,
Won Tun Pada Si Inu Igbo Ti Ko Si Eni To Bi Won Lere Wipe Kilode, ❓Kilofaa❓, Ti Won Fi Gba Emi Lenu Oga Ologun Yii 👀
Iru Ilu Wo Wa Ni Yii Tori Olorun❓ 🙆😭
Awon Osise Ijoba Tun Ya Aworan Pelu Àwọn Ogbontarigi Agbesunmomi Afemisofo Wahala Ti Wa 🙆😭😭👀

Photos from Omo olukotun Taiwo srt's post 25/05/2026
Want your business to be the top-listed Beauty Salon in Ilorin?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Category

Website

Address

Ilorin