ISESE LAGBA TILE TOKO

ISESE LAGBA TILE TOKO

Share

We are here to help each other with our greatest traditional power

We try God did

07/09/2026

IWURE OWURO OJO AJE

Aje karoo
Aje olokun
Aje oniso booji
Asewe dagba
Asagba dewe
Eni ti eru ati omo n fi ojojumo wa Kiri
Iwo ni labomon ti bori aiye
Aje iwo lajiki
Aje iwo lajige
Aje iwo lajipe
Eni amusokun
Eni amusede
Iwo Lani ra Opolo aran a*o oba ti kona yanranyanran.
AJE agba orisha je ki ni e lowo Maje ki ni e lorun.
Aje fi ile mi se ibugbe fi Odede mi se Ibura
Aje o jire Loni O

Ki adura gbogbo wa gba oh





Olodumare thanks for not making me a failure
I will keep grinding to accept more blessing💌

OMO OLOPE ❤️‍🔥

27/08/2026

Eyini lati ran eniti o ba ni isoro nipa tite awon odu Ifa lorisirisi

EJI-OGBE
❗ ❗
❗ ❗
❗ ❗
❗ ❗
OYEKU- MEJI
‼ ‼
‼ ‼
‼ ‼
‼ ‼
IWORI MEJI
‼ ‼
❗ ❗
❗ ❗
‼ ‼
IDI MEJI
❗ ❗
‼ ‼
‼ ‼
❗ ❗
IROSUN MEJI
❗ ❗
❗ ❗
‼ ‼
‼ ‼
OWORIN MEJI
‼ ‼
‼ ‼
❗ ❗
❗ ❗
OBARA MEJI
❗ ❗
‼ ‼
‼ ‼
‼ ‼
OKANRAN MEJI
❗ ❗
❗ ❗
‼ ‼
❗ ❗

OGUNDA MEJI
❗ ❗
❗ ❗
❗ ❗
‼ ‼

OSA MEJI
‼ ‼
❗ ❗
❗ ❗
❗ ❗

IKA MEJI
‼ ‼
❗. ❗
‼ ‼
‼ ‼

OFURUPON MEJI
‼ ‼
‼ ‼
❗. ❗
‼ ‼

OTURA MEJI
❗. ❗
‼ ‼
❗. ❗
❗. ❗

IRETE MEJI
❗ ❗
❗. ❗
‼ ‼
❗. ❗

OSE MEJI
❗. ❗
‼ ‼
❗. ❗
‼ ‼

OFUN MEJI
‼ ‼
❗. ❗
‼ ‼
❗. ❗
OKANRA MEJI
‼ ‼
‼ ‼
‼ ‼
❗. ❗
OGBE OYEKU
❗ ‼
❗ ‼
❗ ‼
❗ ‼
OYEKU OGBE
‼ ❗
‼ ❗
‼ ❗
‼ ❗
IWORI OGBE
‼ ❗
❗ ❗
❗ ❗
‼ ❗
OGBE IWORI
❗ ‼
❗ ❗
❗ ❗
❗ ‼
IDI OGBE
❗ ❗
‼ ❗
‼ ❗
❗ ❗
OGBE IDI
❗ ❗
❗ ‼
❗ ‼
❗ ❗
IROSU OGBE
❗❗
❗❗
‼❗
‼❗
OGBE IROSU
❗❗
❗❗
❗‼
❗‼
OWORIN OGBE
‼❗
‼❗
❗❗
❗❗
OGBE OWORIN
❗‼
❗‼
❗‼
❗❗
OBARA OGBE
❗❗
‼❗
‼❗
‼❗
OGBE OBARA
❗❗
❗‼
❗‼
❗‼
OKANRAN OGBE
‼❗
‼❗
‼❗
❗❗
OGBE OKANRAN
❗‼
❗‼
❗‼
❗❗
OGUNDA OGBE
❗❗
❗❗
❗❗
‼❗
OGBE OGUNDA
❗❗
❗❗
❗❗
❗‼
OSA OGBE
‼❗
❗❗
❗❗
❗❗
OGBE OSA
❗‼
❗❗
❗❗
❗❗
IKA OGBE
‼❗
❗❗
‼❗
‼❗
OGBE IKA
❗‼
❗❗
❗‼
❗‼
OTURUPON OGBE
‼❗
‼❗
❗❗
‼❗
OGBE OTURUPON
❗‼
❗‼
❗❗
❗‼
OTURA OGBE
❗❗
‼❗
❗❗
❗❗
OGBE OTURA
❗❗
❗‼
❗❗
❗❗
mon bo.................
Iranlowo ni odu Ifa yi je fun gbogbo wa o ti a ba ri aside nibe ke bawa tunse nio
OTURUPON OGBE
‼❗
‼❗
❗❗
‼❗
OGBE OTURUPON
❗‼
❗‼
❗❗
❗‼
OTURA OGBE
❗❗
‼❗
❗❗
❗❗
OGBE OTURA
❗❗
❗‼
❗❗
❗❗
IRETE OGBE
❗❗
❗❗
‼❗
❗❗
OGBE IRETE
❗❗
❗❗
❗‼
❗❗
OSE OGBE
❗❗
‼❗
❗❗
‼❗
OGBE OSE
❗❗
❗‼
❗❗
❗‼
OFUN OGBE
‼❗
❗❗
‼❗
❗❗
OGBE OFUN
❗‼
❗❗
❗‼
❗❗

IWORI OYEKU
‼‼
❗‼
❗‼
‼‼
OYEKU IWORI
‼‼
‼❗
‼❗
‼‼
ODI OYEKU
❗‼
‼‼
‼‼
❗‼
OYEKU ODI
‼❗
‼‼
‼‼
‼❗
IROSU OYEKU
❗‼
❗‼
‼‼
‼‼
OYEKU IROSU
‼❗
‼❗
‼‼
‼‼
OWONRIN OYEKU
‼‼
‼‼
❗‼
❗‼
OYEKU OWONRIN
‼‼
‼‼
‼❗
‼❗

OBARA OYEKU
❗‼
‼‼
‼‼
‼‼
OYEKU OBARA
‼❗
‼‼
‼‼
‼‼
OKARAN OYEKU
‼‼
‼‼
❗‼
‼‼
OYEKU OKANRAN
‼‼
‼‼
‼❗
‼‼
OGUNDA OYEKU
❗‼
❗‼
❗‼
‼‼
OYEKU OGUNDA
‼❗
‼❗
‼❗
‼‼
OSA OYEKU
‼‼
❗‼
❗‼
❗‼
OYEKU OSA
‼‼
‼❗
‼❗
‼❗
IKA OYEKU
‼‼
❗‼
‼‼
‼‼
OYEKU IKA
‼‼
‼❗
‼‼
‼‼
OTURUPON OYEKU
‼‼
‼‼
❗‼

19/08/2026
18/08/2026
18/08/2026

WÁRÍ TIE MÚ NBẸ.
AWON ASEJE OWO TO ǸJẸ́ DI OLA

Eyin eyan mi Ekule ooo ṣe daadaa Nimo bayin e gba awon ise yii mosi Fe ijerisi re larin ojo meta si meje .

ASEJE ASINA

Ewe orijin ao lo po mọn ata ìjọsìn mesan ao fi se igbin je ni epo ni iyo

ASEJE OWO

Ewe gure ewe onitikuti ewe sawerepepe ewe Igbo ao lo po mọn ata ìjọsìn mesèn ao fi se eyin adire agiriki merin je ni epo ni iyo

ASEJE OWO

Ewé àjé ewe sawerepepe ewe Igbo ao lopo mọn ata ìjọsìn mesèn ao fi se akuko adire kan je ao ge sí 16 ao sè ni epo ni iyo

ASEJE OWO

Ẹjẹ arọ kan ao gesi meta ao ni geja o ao wa lo ra ẹyẹ onbe mẹta ao lo po mọn ata ìjọsìn mesan ao fi se ẹjẹ arọ na je ni epo ni iyo



ASEJE OWO

Omudun ewe ipin mẹsan omudun ewe lapa funfun mesan ao lopo mọn iyere mesan ao fi po eyin agiriki meta ao ro sí inú ọra kan sọ se ti oba jina ao fi ipepe ge eyin yẹn sí mẹta ao se adura sí ao je

ASEJE OWO

Eyin pẹpeye meta ao kò sí inú isasun ao dà omi agbani sí ao fi se jena ao jeki omi yẹn gbe mọn lara ao se adura sí ao je

ASEJE OWO

Igbin eyo kan ao ge sí 80 itana sawerepepe 80 itana tanapowo 80 ao lo po mọn ata ìjọsìn ao fi se igbin yen je ni epo ni iyo

ASEJE OWO

Iṣu idi tanapowo ao lo pomon iyere mesan ao fi se adire akuko kan je ao ge sí 16 ao fi iru sí

ASEJE OWO

Ewe bomubomu 16 ao ko meje tele inu isasun ao ko eyin agiriki merin le ni ori ao ko ewe yẹn mesan le ni ori ao gbé ka iná ao ni bù omi sí óò yíò jina fún rare ti oba jina ao ko ewe yẹn kuro ao je eyin yé ao wa gun epo eyin yẹn mọn ọsẹ ati ewe yẹn ao mọn fi wẹ



ASEJE OWO

Egbo iyipo ola ao lopo mọn ata ìjọsìn mesan ao fi se eren ewùrà ekiri mesan je pelu ata ìjọsìn mesan ao se ni epo ni iyo

ASEJE OWO

Ekiri ẹran malu mesan ewe sawerepepe ewe aje ao lopo mọn iyere mesan ao se ni epo ni iyo

ASEJE OWO

Onbe mẹta ao lopo mọn ata ìjọsìn mesan ao fi se abo adira dudu je ao ge sí 16 ti obe na bajina ao gbé sí orí ibi to ba gan ao jo kò ni ori apoti ao gbé esane wa me ibikan to ri ese wa ko gbodo kan ile ti u be aba je obe yi lowo a

14/08/2026

EYONU ASHINA AWON AGBA TODAJU

Aofi epo obo tele inu ape aogbe ori okete kan le lori pelu odidi atare kan aowa jo po ao mafi oti lo laro laro

13/08/2026

Aseja asiribibo owo kia kia

Ewe tannapowo 16

Iyere 16

Ao lo gbogbo re papo ao Fi se ponmo maalu tia ge si 16 je lepo niyo

13/08/2026

Ashina owo kia kia

Ewe AGOGO Igun

Epo obo

Eru Alamo

Ao gun gbogbo re papo mo ose wiwe lararo pelu adura

11/08/2026

OGUN AWEBI DANU

ewe ejinrin pelu ori ao gun pomo ose dudu ao ko sinu ike
funfun, ao koko lo fi we ni odo ton san kia to ma fi iyoku we
ni ile.

fans

Want your business to be the top-listed Beauty Salon in Gwagwalada?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Category

Website

Address


Gwagwalada

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when ISESE LAGBA TILE TOKO posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Subscribe

We will notify you when anything happens in Gwagwalada.